Hospice of the Western Reserve ba ilana ijọba apapọ lori ofin etọ ara ilu ati pe a ko gbọdọ ṣe ojuṣaaju nipa ẹya, àwo, ilu-abinibi, ọjọ-ori, abarapa tabi jijẹ ọkunrin tabi obinrin. Hospice of the Western Reserve wọn ko gbọdọ yọ awọn eniyan silẹ tabi wuwasi wọn yatọ l'atari eyà, àwo, abinibi, ọọ-ori, tabi jijẹ ọkunrin tabi obinrin.
Hospice of the Western Reserve:
- Npese-ohun-elo ọfọ ati iranlọwọ fun awọn alaabọ-ara lati le sọrọ ni ọna ti omunadoko, bii: oAkọṣẹmọṣẹ ogbufọ odi
- oKikọo ọrọ jade ni ọna miran (kikọ ọrọ ni titobi, agbohunsilẹ, awọn ohun-elo igbalode fun ẹrọ ayelujara ati awọn ọna miran.)
- A npese ogbufo l'ọfẹ fun awọn ti èdè abinibi wọn kìí ṣe èdè GẹẹsioAkọṣẹmọṣẹ ogbufọ
- oKikọ ọrọ ni awọn èdè miran
Bi o ba nfẹ awọn anfani wọnyi, kansi 216.383.6688.
Bi ẹ ba nigbagbo wipe Hospice of the Western Reserve ti kuna lati ṣeto awọn iranlọwọ wọnyi tabi ṣe ojuṣaaaju ni awọn ọna miran bi ẹlẹyamẹya, ilu-abinibi, ọjọ-ori, abarapa, tabi jijẹ ọkunrin tabi obinrin, le fi iwe kotẹmi-lọrun/iwe ifẹhonu han si:
Mary Kay Tyler, Vice President of Quality
17876 St Clair Ave.
Cleveland, OH 44110
216.383.6688
MKTyler@hospicewr.org
Ẹ le fi iwe ifi ẹhonu han ni ojukoroju tabi nipa fifi ranṣẹ ni apo-iwe si adirẹsi wa, faksi, tabi ẹrọ-ayelujara. Bi ẹ ba nilo iranlọwọ lati kọ iwe ifi-ẹhonu han, Rebecca Patrick wa ni sẹpẹ fun yin.
Ẹ tun le pe kotẹmilọrun l'atari etọara-ilu pẹlu U.S Department of Health and Human Services, Office for Civil Rights, Office fun Civil Rights Complain Portal, wa ni https://ocrportal.hhs.gov/ocr/portal/lobby.jsf tabi nipa fifi iwe-sọwọ tabi lori ẹrọ-ibanisọrọ ni:
U.S. Department of Health and Human Services 200 Independence Avenue, SW Room 509F, HHH Buiding Washington, D.C 20201 1-800-368-1019, 800-537-697 (TDD) Ẹ le ri fọọmu fun ẹhonu ni http:/www.hhs.gov/ocr/office/file/index/html.
Translation provided by US Dept of Health and Human Services 26 July 2016